Genesis 15:5-6

5 aOlúwa sì mú Abramu jáde sí ìta ó sì wí fún un pé, “Gbé ojú sókè sí ọ̀run kí o sì ka àwọn ìràwọ̀ bí ó bá ṣe pé ìwọ le è kà wọ́n.” Ó sì wí fun un pé, “Nítorí náà, báyìí ni irú-ọmọ rẹ yóò rí.”

6 bAbramu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.

Copyright information for YorBMYO